Video Eleda » Qdot Lyrics | Musica Afro

Ver Video y Lyrics con la música del Genero Afro más popular de Qdot y otros artistas en línea. Disfruta de las mejores canciones de 2025 en LetrasFM de música en línea. ¡Encuentra tu canción favorita y escúchala en cualquier momento y en cualquier lugar!

Video Eleda » Qdot Lyrics

Qdot - Eleda Lyrics


Iji ra ale, aleka malaika (aleka malaika)
Ijimi ma serifu malaika mi
Qdot lórúko mí

Bàbá lókè má fí mí sí one corner
Àgbà dé kàn tó gb'ohùn Rolling Dollar
Má ṣe mí l'Aboki oníṣẹ́
Bàbá, dàkún, ṣé mí lọmọ aláṣelà
Ṣébí, alapata lo lọ'run ẹran

Má sọ pé ó dán ìgbàgbọ' mí wo
K'ayé má bá tú mí l'aṣọ wo
Ọmọ Adeboye ó gbọ'dọ' wọ ẹkùn ègùn
Ọmọ alapata ó gbọ'dọ' jẹ egungun
Ṣé mí ní dá rocha, má ṣe mí l'alakisa
Ọlọrun àwọn Ọlọrun

Mó tí gbé Bíbélì, gbé Qurani (mo gbé oh)
Mó tí fití Késárì fún Késárì (fún Késárì)
Mó tí lo church, mó tí lọ mosa'asi
Àgbàlagbà mo' mí dáa lọ yí

Ẹlẹdà má sún (ẹlẹda mí má sún)
Ẹlẹda má sún (ẹlẹda má sún)
Ẹlẹda mí má sún (woah)

Mó gbàgbọ' pé ọmọ Ọlọrun ní Jésù
Mó gbàgbọ' pé òjíṣẹ́ rẹ l'Anọbi (sallallahu 'alayhi wa sallam)
Ọlọrun ó ṣebì èèyàn lo ń ṣe'ka
T'ayé bà bínú wọn má ní kí Eyimba na Barça pàá oh

Qudus ó mọ pé ogún láyé oh
Ń bá rà ìbọn, ń bá rà 'dá
Àwọn tẹ gbà'yé fún, kó ṣ'ojú àyé
K'oma f'áyé mí t'afala
Àdàbà tí ko lé fo mọ, oh-ohh
Ọmọ aráyé lo tún dáa

Mó tí gbé Bíbélì, gbé Qurani
Mó tí fití Késárì fún Késárì
Mó tí lo church, mó tí lọ mosa'asi
Àgbàlagbà mo' mí dáa lọ yí

Ẹlẹda má sún (ara eli Mikail)
Ẹlẹda má sún (ara 'ba malaika fali mi)
Ẹlẹda mí má sún (e li kulu modá bara n kadu 'lifa)
Ẹlẹda má sún (ẹrí ń bẹ lókè Agelu)
Ẹlẹda mí má sún (sata ta ulehu)
Ẹlẹda má sún (orí mí jọọ-)

Mà jẹ ń d'àgbàya kín tó d'olówó oh-oh
Ẹ'dá mí jọọ (orí mí jọọ oh)
Alola fari gi noti, seri moda fa'yallahu (fa'yallahu)
Bàbá dá mí lóhùn (dá mí lóhùn)
Àgbà dé eee (àgbà dée)
Àgbà dé kàn tó gb'ohùn Rolling Dollar
(Yeah, ayy-ayy-ayy)
(Bàbá dá mí lóhùn)

Fali uli faki ilaina (ẹlẹda má sún)
(Yeah, who's here?)

Eleda » Qdot Letras !!!
Esta web no aloja ningun archivo mp3©LetrasFM.Info 2025 Colombia - Chile - Argentina - Mexico. All Rights Reserved.

Musica Online, Escuchar musica online , Musica En Linea, Musica en linea gratis, Escuchar Musica Gratis, Musica Online 2025, Escuchar Musica

Musica 2025, Musica 2025 Online, Escuchar Musica Gratis 2025, Musica 2025 Gratis, Escuchas, Musica de Moda.