Ayy, uh-uh-uh-uh
Uh-uh
Masowi fun mi wuu, kali kudi
(Wo, ah!) Ogugulisọ
I'da liki mufa 'ya teli ka
Seri moda elèdè kewu
Fati litu fi kamu'ri
Ofu'u fami nuti uti wi'ah
B'omi ṣe wọnú àgbọn, kos'ẹni t'oye (kò ṣeni t'oye)
Bi mo ṣe ń gba level mí, ṣé b'ẹmi loye (ṣé b'ẹmi loye)
Alert dey enter, alert dey enter, ìyanu
Na me for Canada, na me for America, Ìyanu (ìyanu)
Alert dey enter, alert dey enter, ìyanu (ìyanu)
Na me for Canada, na me for America, ìyanu
Uh-uh
Ojojúmọ mo fi ń gbàdúrà (mo ń gbàdúrà)
Hmm (ye) mo ń gbàdúrà, k'àyé mí dára (k'àyé mí dára)
Wọn fẹ mọ motor, tí mo wọ de'lẹ ìlérí mí (wọn fẹ mọ, yea)
Kẹkẹ Elijah mo gbé, ẹ lerí mí
Bàbá mí a pemi ní Qudusi
Mummy a pemi ni Damilare
Ìyàlẹ́nu lo jẹ, ọmọ yi padà ṣ'orí ire
Àwa tí lọ k'afárá to ja (k'afárá tó ja)
Oya wọn lẹ'nu, mo ṣe gòkè àgbà (mo ṣe gòkè àgbà)
B'omi ṣe wọnú àgbọn, kos'ẹni t'oye (kò ṣeni t'oye)
Bi mo ṣe ń gba level mi ṣé b'ẹmi loye (ṣé b'ẹmi loye)
Alert dey enter, alert dey enter, ìyanu (ìyanu ni)
Na me for Canada, na me for America, ìyanu
Alert dey enter, alert dey enter, ìyanu
Ahh, na me for Canada, na me for America, iyanu
Ìṣẹ tí mí o ṣe, wọn san'wó ẹ (ehn-ehn, ahh)
O má di gobe, tẹ bá w'ojú ẹ
Dákun, bámi náwó mí, dákun, bámi náwó mí (bàbá tí ja'wó)
Dákun, bámi gb'owó mí, dákun, bámi gb'owó mi (jẹ n sọ lo wi)
Allow me, allow me to enjoy my life
You dey doubt me, you dey doubt me
When we dey come your house
Ojo tí paa 'kumọ, ọjọ tí pẹ
Ìrìn àjo mí ki ń ṣe kéré ní
Ò t'afà sókè, yido b'orí
Àwa tí ja'we olu b'orí (milẹ, milẹ)
B'omi ṣe wọnú àgbon, kos'ẹni t'oye (kò ṣeni t'oye)
Bi mo ṣe ń gba level mí, ṣé b'ẹmi loye (ṣé b'ẹmi loye)
Alert dey enter, alert dey enter, ìyanu
Na me for Canada, na me for America, ìyanu
Alert dey enter, alert dey enter, ìyanu
(Yeah, who's here?)
Na me for Canada, na me for America, ìyanu