Mo ṣe b'onílé ọlá, Ọba le-le ṣe'ni
Ibà rẹ Olódùmarè
Ọba tiń-tin ti bẹ latilé ọ wá
Ọba àdake dájọọ
Ìwọ lo d'áyé, ìwọ lo d'ọrùn
Ìwọ lo mọmí, ìwọ lo mọọmi
Ọba àpáàní, jiní, àjíni, pàání
Ọba ìgi Árábà, t'àrà o le fayaa
Àgó onílé (ibà oh), ayy-ayy, oh-oh (ibà oh)
Àgó àlejo, k'onílé, mo k'àgò oh (ibà oh)
Ọmọ yìn tidé oh
Ewúré to wọlé tikó k'àgo
Ìyẹn d'ẹran àmúso
Ibà oh, ibà oh
Ibà, ibà oh
Ibà Akọdá, ibà Àṣẹda oh
Ibà, ibà oh (ibà oh)
Àyé to-to, àyé àkamara
Ibà oh, ibà oh
Mo ṣé ibà awọn t'Ọlọrun mí gb'àyé fún (ibà oh, ibà oh-o)
Ibà ohh (ibà oh)
Ibà (ibà oh)
Ki ibà ṣẹẹ (ibà oh)
Ẹbẹ mo b'ẹ'yin to láyé (ibà oh)
Ẹ jẹ' kí ibà jumí ṣe (ibà oh)
Ibà rẹ Olódùmarè (ibà oh)
Ọba to fún lénu, ibà oh (ibà oh)
To dáàlu, to tún wá dá orin (ibà oh)
Mo ṣe ibà àwọn t'okọ k'ọrin, gbess!
Ibà jumí ṣe oo, ah (ibà oh-ohh)
Ah, no be say I too sabi (yeah, ayy-ayy)
Na prayer dey work for me
Ìyá t'obí mí o dakẹ àdúrà
Ọmọ onipọn, bolaa-molaa
I'm makin' muller with my vernacular oh
(Ibà oh) ibà o (ibà o), mí o ṣe'ni dúpẹ tèmi
Ibà, ibà, ibà, ibà-a (ibà oh)
Àwọn kàn tí kọ ke mí to dée
Bẹẹ, bèmi bá lọ, àwọn kàn má kọ
(Sweet mix by Drumphase)
Ibà (ibà o)
Ibà obìnrin, ibà ọkùnrin oh (ibà oh)
Ibà ọmọdé, ibà àgbàlagbà (ibà oh)
Ibà àwọn t'otí kọ kiń to má kọ (ibà oh)
Ibà àwọn tóótun má kọ tińbá sí mọ ohh (ibà oh)
Ibà àwọn tí wọn tí ṣ'orin wọn, t'ọṣi má kọrin (ibà oh)
Ibà-ah (ibà oh)
Ahh-ayy oh, ibà